ADÉLABÚ KÍ ÀWỌN KRÌSTÌẸ́NÌ KÚ ỌDÚN ÀJÍǸDE
ÀGBÀAKIN Pàràkòyí Ilẹ̀ Ìbàdàn tó tún jẹ́ olùdíje fún ipò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òsèlú APC nínú ìbò ọjọ́ kẹsàn-án osù kẹta, ọdún 2019 ti kí gbogbo ọmọlẹ́yìn Krístì kúu pọ̀pọ̀sìnsìn ayẹyẹ ọdún Àjíǹde tó ń lọ...
Read More